Tí Ọlọ́run kan ṣoṣo bá wà, nígbà náà, ó yẹ kí a máa tọ́ka sí Ọlọ́run ní oníkan ṣoṣo.
Síbẹ̀síbẹ̀, nínú Bíbélì, Ọlọ́run tún ń tọ́ka sí nínú ọ̀nà pọ̀, “Àwa.”
Kódà ní òní, ọ̀rọ̀ náà “Àwa” ṣì jẹ́ àdììtú fún ọ̀pọ̀ àwọn òjíṣé Bíbélì, ṣùgbọ́n Kristi Ahnsahnghong ṣí ìtumọ̀ tó fara sin hàn.
Ọlọ́run, ẹni tí ó dá akọ àti abo ní àwòrán ara Rẹ̀ tí ó sì fúnni ní ìyè àìnípẹ̀kun ní ìgbà Ẹ̀mí Mímọ́, ni Ọlọ́run Baba àti Ọlọ́run Ìyá.
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy